MALA NI KI EKILO FUN TI E BA NRI, he should be himself and stop abusing the one and only King of Fuji, K1, oluaye, i was embrassed to be mala fan when i heard him abusing Alhaji K1 like that, no matter what he need to be patient in whatever he want to do.
i still remain his fan and i promise to always be, but he should let peace rain, even oba agbereoju gan ti sober, then what next, se arabambi loye ko tun ma ba arawon ja. Alhaji, oba new generation erora ooooooooooo.
__________________
God is good all the time & all the time God is Good
you shall never regret to meet me in your life.
Ekunola Gbenga A
Thank so mush for ur post I like it , Gbogbo fan eso fun Alayeluwa enough is enough he should stop abusing K1 is the one who called him is Father why is he abusing is Father for God sack , nitoto oro is a thing ti Alayeluwa furare ba bere lowo K1 pe kini owun se fun Gbogbo fan eyo eje ki a ko se Anobi ki ani suru ejeki aran ti nigba ti omo anobi ku anobi ni suru ni kani o soro si Oloun ni ko olohun abinu si ... Loto omo kekere ni mo jeoo amo Aliamdulilahi lakajewa Mala baba alaje u have to change apologis good luck bye
though, i am not member of this fan/club before, but i was amused with Olugbenga posting, he is a good ambasador of fuji music, i will jst like to caution Mala and even Rahma to be careful, do not try to defend mala, no amount of K1 mistake should amount for such abusive words from mala. Rahman you urself, you have said it all, in gratitude 3 in one, i heard it mala abused k1 and he promised not to repeat it, it that a good way of showing his gravances. Ti mala ba ni itiju, nise loye ko lo ba Alhaji nile or he should report him to Otunba General Paso.
so, Alhaji, awa nife yin oooooooo, so ema bawon buyan ooooooo, Rahman ma defend Oba generation, let him go and apologise
Ekaro gbogbo omo karo ojire ohun ti emi ni lati so nipe kosi oba meji lagbole fuji toju king dr ahl saeed osupe montagbamonle olufimon akoko lo orin re nkowalogbon ati wipe afi orin gbe asaga ni osupa nibi gbogbo koda ni ilu awon oyinbo won gba tie kilowade ti awon arabanbi fi dite osupe ninu awon arabanbi kiti si eniti olekorin ti osupa nko mi osi tiri eniti ole korin bi saeed osupa tori naa ki awon arabanbi olojawo ninu ote ki tori pe ti won obajawo ninu ote won ma godo kanhin ayewon nii awa ebi olufimon pojuwon lo nile loko kosi ibi ti kotisi ebi olufimon emi ti monsoro yi lowolowo ilu cote d'ivoire ni mowa nitori naa eso fun won pe ki won ti owo omo won bo aso ki won ma ba te ki esi sofun wasiu alabi pasuma pe kolosinmi agbaja pe won k,an ba oyaja lasan nii sango loni sere oro mi ojubayi lo